Ezzaki Badou
Ezzaki Badou ni a bini ọjọ keji, óṣu kerin (April), ọdun 1959 ti inagijẹ rẹ njẹ Zaki jẹ a-ko-ni-mo-o-gba (coach) ere bọọlu alafẹsẹgba ati elere tẹlẹ ri to ṣèrè gẹgẹbi asole (goalkeeper) órilẹ ede Morocco[1][2][3][4].
Iṣẹ Ezzaki[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ezzaki ṣoju AS Salè, Wydad AC, RCD Mallorca ati Fath Union gẹgẹbi elere bọọlu Alafẹsẹgba. Arakunrin naa kopa ninu ife eye ere bolu orile-ede agbaye ti a mo si FIFA Cup ti ọdun 1986 ati ife eye orile-ede Afirica ti a mo si African Cup of Nation leemẹrin[5][6].
Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ni ọdun 1986, Ezzaki ni a ọ ni elere bọọlu afẹsẹgba ti ilẹ afirica lẹyin naa ni elere naa yege ninu La Liga ni ọdun 1989 nibi to ti gba Ife ẹyẹ ti Ricardo Zamora[7]. Ezzaki gba elere to pegede julọ ni órilẹ ede Morocco ni ọdun 1979, 1981, 1986 ati 1988. Ni ọdun 1986, Ezzaki jẹ elere bọọlu afẹsẹgba CAF ti ilẹ afirica[8][9] Ni ọdun 2017, Badou jẹ coach to pegede julọ ni ilu Algeria[10].
Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ Zaki Badou
- ↑ Badou Ezaki Biography
- ↑ Ezzaki Badou "Zaki" - International Appearances
- ↑ Badou Zaki
- ↑ Ezzaki Badou
- ↑ African Nations Cup 2004
- ↑ African Player of the Year
- ↑ Exceptional World Cup in Mexico '86
- ↑ African Football (CAF) for the title of the best player
- ↑ Zaki crowned best coach for the year 2017