Patricia Kihoro
Patricia Kihoro | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Patricia Wangechi Kihoro 4 Oṣù Kínní 1986 Nairobi, Kenya |
Orílẹ̀-èdè | Kenyan |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2004–titi di isinyin |
Website | patriciakihoro.com |
Musical career | |
Irú orin | |
Patricia Wangechi Kihoro (ti a bini ojo kerin osu kini odun 1986)[2][3] je osere, olorin ati adari eto radio ti owa lati ilu Kenya. O di olokiki nitori pe o kopa ni ipele eketa titi Tusker Project Fameeleyi ti o de igbeyin idije na. Ni pa sise ere, akoko ere ti o kopa ninu re je ere Miss Nobody eleyi je ki o gba yiyan ninu ami eye Kalasha Awardsasiwaju osere ti odara julo ni odun 2012. Ninu jara tv o je okan ninu osere ti o pataki julo ninu Groove Theory fiimu olorin, osi kopa ninu Demigods, Changes, Rush ati Makutano Junction.[4] Gegebi osise redio oti sise pelu One FM ati Homeboyz FM.[5][6]
Igbesi aye ibẹrẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Won bi Kihoro ni osu kini odun 1986, osi dagba si Nairobi, olosi ile iko Shepherd Junior Primary School fun eko akobere, lehin na olosi Moi Girl's School, ni Nairobi. O lo si ile eko giga titi Moi Universitynibi ti oti keko science ati psychology. Ni ile eko giga ni oti lo dije ni Tusker Project Fame.[7]
Ise[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Odun 2009 si 2012[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ni osu keta odun 2009, Kihoro ko pa ninu ayewo fun awon ti o ma kopa ninu Tusker Project Fame. ni odun 2010 won lo ninu ere orin fun orin Just a Band ha-he ti o da lori akoni Makmende.[8] Ni odun 2011 o ko ipa Pet Nanjala ni jara Changes.[9]Ni odun 2011 kana otun kopa ninu ere Miss Nobody, eleyi ni o je ki won yan fun ami eye Kalasha ni odun 2011. Ni odun 2012, owa lara awon ti okopa ninu fiimu orin ti akori re je Groove Theory. O ko ipa Biscuit, ololufe Zamm ninu ere ti oda lori igbesiaye awon omo ile eko Victoria University.[10]
Odun 2013 si 2014[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ni odun 2013 o ko pa ninu ereori telifisonu The Fattening Room[11]eleyi ni oje ki ohun ati awon alajosise se awokose asa ti awon eyan Efik ni apa guusu orile ede Nàìjíríà.[12] ni odun 2014 oko ipa Nana ninu jara Rush.[13]O se ere pelu Janet Mbugua, Wendy Kimani, Wendy Sankale and Maryanne Nundo.[14]
Odun 2015 titi di akokoyi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ni odun 2015, o ko ipa omo Maqbul Mohammed ninu jara Makutano Junction. Ni odun 2018 Kihoro ko ipa Josephine, iyawo titun si ikan ninu awon akopa iwaju titi fiimu Rafiki
Aworan iwoye[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Odun | Nikan (awọn) | Oludari | Awo-orin | Ref (awọn) |
---|---|---|---|---|
2011 | "Nakupenda" | rowspan=2 style="background: #ececec; color: grey; vertical-align: middle; text-align: center; " class="table-na" | TBA | ||
Ọdun 2013 | "Loving Wrong" (Calvo Mistari ti o ṣe afihan Patricia Kihoro) | Edu G |
Asayan ere[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Awọn fiimu ati tẹlifisiọnu[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Odun | Akole | Ipa | Akiyesi |
---|---|---|---|
2009 | Tusker Project Fame | Ara e | Odije pari |
2011 | Miss Nobody | Juliette | fiimu kukuru |
2011 | Changes | Petronilla Nanjala | |
2011–13 | Demigods | Mona | |
2012 | Mali | Ara e | ere ipele kan |
2012 | Out of Africa – A Safari Through Magical Kenya | Ara e | |
2012–14 | Groove Theory | Biscuit | |
2013 | Homecoming | Alina | Fiimu kukuru |
2013 | Life in a Single Lane | Ara e | |
The Fattening Room | Ara e | ||
2014 | There is Nothing to Do in Nairobi | Patience Omondi | Fiimu kukuru |
2014 | Rush | Nana | |
2015–present | Makutano Junction | – Mabuki | Jara |
2018 | Thomas and Friends Big World! Big Adventures! | Nia (ohun akorin) | Fiimu |
2018 | Discoonnect[15] | Judy | Ere ife |
2018 | Rafiki | Josephine | Film |
Odun | Ẹgbẹ | Ẹka aami ẹbun | Iṣẹ ti a yan | Esi | Ref (awọn) |
---|---|---|---|---|---|
2012 | Kalasha Awards | Oṣere Aṣere ti o dara julọ ninu Fiimu kan | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé |
Awon itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 "Reverbnation: Patricia Kihoro". Reverbnation. Retrieved 1 February 2015.
- ↑ "S3xy Homeboyz Radio presenter Patricia Kihoro reveals her age and leaves many surprised!". Mashada. Retrieved 1 February 2016.
- ↑ "Patricia Wangechi Kihoro profile". World of Big Brother. Archived from the original on 1 April 2019. Retrieved 1 February 2016.
- ↑ "Patricia Kihoro". Talent East Africa. Retrieved 5 February 2016.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Chrysanthus Ikeh. "Patricia Kihoro to host shows with Homeboyz Radio 103.5". The Net. Retrieved 5 February 2016.
- ↑ "Patricia Kihoro Lands New Radio Job". Nairobi Wire. Retrieved 5 February 2016.
- ↑ "Patricia Kihoro-Rising to the top of Kenyan showbiz industry". SDE. 23 September 2015. Archived from the original on 25 July 2018. Retrieved 3 February 2016.
- ↑ Vinograd, Cassandra (March 24, 2010). "Kenya Launches Country's First Viral Music Video". the wall street journal. https://blogs.wsj.com/speakeasy/2010/03/24/kenya-launches-countrys-first-viral-music-video/.
- ↑ "HOT: Patricia Kihoro". Kenya Buzz. Archived from the original on 12 July 2016. Retrieved 3 February 2016.
- ↑ "KENYA'S 1ST MUSICAL TV DRAMA SERIES- THE GROOVE THEORY". Actors.co.ke. 4 December 2013. Retrieved 3 February 2016.
- ↑ Lasisi, Oluwafunke (28 April 2013). "EbonyLife Brings Six African Ladies to The Fattening Room". This Day Live. Retrieved 5 February 2016.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Fattening Room". Ebony Life TV. Archived from the original on 18 November 2021. Retrieved 5 February 2016.
- ↑ "Rush; Kenyas version of sex and city". In The Loop. Retrieved 5 February 2016.
- ↑ Baba Ghafla (18 April 2012). "Rush: New TV series packed with celebs". Ghafla!. Retrieved 5 February 2016.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ https://www.imdb.com/title/tt8413566
Awọn ọna asopọ ita[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- Official website
- Patricia Kihoro at SoundCloud
- All articles with dead external links
- Articles with dead external links from September 2023
- Articles with invalid date parameter in template
- Articles with permanently dead external links
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- Articles with dead external links from March 2018
- Articles with dead external links from May 2020
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1986